Ifa


Ifa jé òrìsà kan pàtàkì láàrin àwon Yorùbá. Àwon Yorùbá gbàgbó wí pé Olódùmarè ló rán ifá wá láti òde òrun latí wá fi ogbón rè tún ilé ayé se. Ogbón, ìmò, àti òye tí olódùmarè fi fún ifá ló fún ifá ní ipò ńlá láàrin àwon ìbọ ní ile Yorùbá. “A-kéré-finú-sogbón” ni oríkì ifá.
Ìgbàgbó Yorùbá ni wípé ní ìgbà kan rí, ifá gbé òde-ayé fún ìgbà pípé kí o tóó padà lo sí òrùn. Ní ìgbà tí ifá fi wà ní ilé ayé, ó gbé ilé-ifè fun ìgbà péréte. Sùgbón ní ìgbà tí òrùnmìlà fi wà láyé yìí naa, a tún maa lo sí òde òrun léèkòòkan tí olódùmarè bá pèé láti wá fi ogbón rè bá òun tún òde-òrùn se. Nítorí náà gbáyégbórun ni ifá ńse.
Ìtàn so fún wa wipe omo méjo ni òrúnmìlà bí nígbà tí ó wà láyé, nígbà tí ó di ojo kan ti òrùnmìlà ńse odún ni òkan nínú àwon omo yìí tíí se àbíkèhìn pátápátá báse àfójúdi sí òrúnmìlà, ni òrùnmìlà bá binú fi ayé sílè lo sí òde orun. Ni ìfá bá relé olókun kòdé mó. Ó léni té bá ri i, e sá maa pè ní baba”. Sùgbón òrùnmìlà fún àwon òmo rè méjèèjo náà ní ikin mérìndínlógùn ó ní be e délé bee bá fówóó ní, eni tè é maa bi ninu.
Ifa.Is the word of Olodumare encompassing all knowledge of things past, present and future. It is sometimes used interchangeably as the name for the orisha deity Orunmila. Orunmila is the orisha of wisdom and knowledge, who created the system and method for accessing the knowledge of Ifa. Ifá refers to the system of divination and the verses of the literary corpus known as the Odú Ifá. Yoruba religion identifies Orunmila as the Grand Priest; as that which revealed Oracle divinity to the world. Such is his association with the Oracle divinity; in some instances, the term "Orunmila" is used interchangeably with Ifa .  

Ifá refers to the system of divination and the verses of the literary corpus known as the Odú Ifá. Yoruba religion identifies Orunmila as the Grand Priest; as that which revealed Oracle divinity to the world. Such is his association with the Oracle divinity; in some instances, the term "Orunmila" is used interchangeably with Ifá.
Comments